Ìwé atọ́nà fún ààbò SEEMO
Ìwé atọ́nà fún ààbò SEEMO: Ìwé atọ́ni sónà fún àwọn oníròyìn tí Wọ́n ń ṣe àkànṣe iṣẹ́ tàbí lórí ìṣẹ̀lẹ̀ pájáwì: Ìwé ìléwọ́ yìí jáde láti ilé iṣẹ́ Ìròyìn Gúúsù…
Ìwé atọ́nà fún ààbò SEEMO: Ìwé atọ́ni sónà fún àwọn oníròyìn tí Wọ́n ń ṣe àkànṣe iṣẹ́ tàbí lórí ìṣẹ̀lẹ̀ pájáwì: Ìwé ìléwọ́ yìí jáde láti ilé iṣẹ́ Ìròyìn Gúúsù…
Ìkọ́ni àti ìdanilẹ́kọ̀ọ́ Ọ̀kan gbòógì lára ojúṣe GIJN ni láti se àkójọ pọ̀ atọ́nà fún ìwádìí tó múná dóko lórí ìròyìn yín. Onírúurú àwọn èdè ni ẹ yí ò rí…
Láti o̩wó̩ Raymond Joseph | O̩jó̩ Ke̩rìnlélógún, Os̩ù Ògún, 2021 GIJN ti s̩e àfikún ató̩nà oní-sísè̩-n-tè̩lé wa lórí níní àrídájú lórí àwo̩n àwòrán láti mò̩ bóyá àwòràn tí e̩ ń rí lórí ayélujára jé̩…
Àwọn oníròyìn Àdáṣe máa ń sábà wà láàyè ara wọn nígbà tí ó bá di ọ̀rọ̀ ààbò, lójú aye àti ìmọ̀ ẹ̀rọ ayélujára, ṣùgbọ́n ọ̀pọ̀ ohun-èèlò aṣèrànwọ́ ló wà. Ìrànlọ́wọ́…
Ìpàdé Àpérò lórí Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Àwọn ìpàdé àpérò wọ̀nyí pèsè àǹfààní lóní yanturu láti mọ àwọn ènìyàn sii, láti…
Ríró àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn aládàńi ní agbára: Ìlàkàkà ilẹ̀ Amẹ́ríkà láti fún àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn ní ààyè láti ṣíṣe láì ní ìdíwọ́ àti ẹ̀rọ ayélujára jákèjádò orílẹ̀ èdè…
Láti o̩wó̩ Kira Zalan | May 23, 2016 Ǹjé̩ e̩ ń wá àwo̩n orísun? Rírí onímò̩ ní apá ibì kan jé̩ ibi tí ó dára láti bè̩rè̩ fún ò̩pò̩ ìtàn. GIJN s̩e àyè̩wò…
Ohun èlò fún àwọn oníròyìn: ìwé atọ́ni sónà olójú ewé ọgọ́rùn-ún ó lé méje èyí tí ilé iṣẹ́ Amẹ́ríkà tó ń rí sí oko òwò aládàńi gbé jáde lọ́dún 2009…
Jọ̀ ó tẹ “tókàn” láti bẹ̀rẹ̀. Irinṣẹ́ Fún Àgbéyẹ̀wò Ààbò Àwọn Oníṣẹ́-Ìròyìn (JSAT) dàgbàsókè fún ìlò àwọn Alábàáṣepọ̀ GIJN àti àwọn Oníròyìn káàkiri àgbáyé. Lórí ìparí, irinṣẹ́ fún àgbéyẹ̀wò máa…
Wọ́n gba àwọn Oníròyìn ní ìyànjú gidigidi láti dá ààbò bo àwọn ìbánisọ̀rọ̀ wọn àti àwọn ìròyìn wọn láti dènà ìruga sókè ìhalẹ̀mọ́ni. Síbẹ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀kọ́ ṣe àfihàn pé…