Iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn
Ohun èlò fún àwọn oníròyìn: ìwé atọ́ni sónà olójú ewé ọgọ́rùn-ún ó lé méje èyí tí ilé iṣẹ́ Amẹ́ríkà tó ń rí sí oko òwò aládàńi gbé jáde lọ́dún 2009…
Ohun èlò fún àwọn oníròyìn: ìwé atọ́ni sónà olójú ewé ọgọ́rùn-ún ó lé méje èyí tí ilé iṣẹ́ Amẹ́ríkà tó ń rí sí oko òwò aládàńi gbé jáde lọ́dún 2009…
Ìpàdé Àpérò lórí Iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Àwọn ìpàdé àpérò wọ̀nyí pèsè àǹfààní lóní yanturu láti mọ àwọn ènìyàn sii, láti…
Is̩é̩ tí ó gbo̩ngbó̩ nípa sís̩e is̩é̩ ìròyìn o̩ló̩fintótó lè sú ènìyàn látàrí orís̩irís̩i àgbéyè̩wò ajé̩mó̩-ìs̩èlú. Ohun èlò yìí mójú tó díè̩ nínú àwo̩n àdojúko̩ tí àwo̩n adás̩é̩s̩e àti àwo̩n…
Àwọn Akẹ́kọ̀ọ́ tó jẹ́ ti ilẹ̀ Òkèèrè, tí wọ́n ń dé padà láti Àwọn Orílẹ̀ Èdè tí Àjàkálẹ̀ Àrùn kò fi bẹ́ẹ̀ bá fínra gbé Òṣùwọ̀n COVID-19 ju ti Amẹ́ríkà…
Àwọn Èrò Oní-àdéhùn Ìdúnàádúràá Àdéhùn fún Átíkù Oníwàádìí gbọ́dọ̀ bo onírúurú ìṣòro tí kò fi bẹ́ẹ̀ yẹ fún, sọ pé àbùdá nípa ọmọ ọlọ́ńgbò tó rẹwà. Àwọn kókó kan tó…
Crafting Investigative Reportage Into Dramatic Narratives, láti o̩wó̩ Vinod K Jose, Olùs̩àtúnko̩ àgbà fún The Caravan, Ìwé ìròyìn àkó̩kó̩ fún is̩é̩ ìròyìn aláròyé àti o̩ló̩fintótó ní ilè̩ India. Àgbékalè̩ GIJC19 …
Àpèjúwe àti àwọn ètò ẹ̀kọ́ lórí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn [Ní sísẹ n tẹ̀lé álífábẹ́ẹ̀tì orúkọ àwọn Fáṣítì gbogbo àti àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n]. Aligọ́rídìmù fún àwọn Oníròyìn Àkànṣe iṣẹ́ sílábọ́ọ̀sì tí…
Ìmò̩ràn lóri kókó ìs̩èwádìí máa ń wáyé ní orís̩irís̩I ò̩nà – kìí s̩e fún onís̩é̩-ìròyìn o̩ló̩fintótó nìkan, s̩ùgbó̩n fún o̩ló̩pàá, agbanisís̩é̩, agbe̩jó̩rò, onís̩é̩ ìlú, àti àwo̩n yòókù. Nǹkan tó fojú…
Ìfúnnilówó Owó-ìrànwọ́ fún àwọn iṣẹ́-àkànṣe ìjábọ̀ wà láti onírúurú orísun. Àwọn Olùfúnnilówó kan gba gbogbo irúfẹ́ àbá wọlé, nígbà tí àwọn mìíràn wá láti ṣe ìrànwọ́ fún àwọn àkórí kan…
Ìtalólobó àgbà-ọ̀jẹ̀ fún wíwú gbòǹgbò ìròyìn-èké Láti ọwọ́ Maurice Oniang’o | ọjọ́ kẹtà-lé-lógún oṣù kọkànlá, ọdún 2021 Fún àwọn oníròyìn aṣèwádìí tí wọ́n ń wú ìpòlongo tí ìròyìn tí kò…