Ìdáṣe: Ìfúnnilówó Iṣẹ́-àkànṣe Oníwàádìí Tìrẹ
Ìfúnnilówó Owó-ìrànwọ́ fún àwọn iṣẹ́-àkànṣe ìjábọ̀ wà láti onírúurú orísun. Àwọn Olùfúnnilówó kan gba gbogbo irúfẹ́ àbá wọlé, nígbà tí àwọn mìíràn wá láti ṣe ìrànwọ́ fún àwọn àkórí kan…
Ìfúnnilówó Owó-ìrànwọ́ fún àwọn iṣẹ́-àkànṣe ìjábọ̀ wà láti onírúurú orísun. Àwọn Olùfúnnilówó kan gba gbogbo irúfẹ́ àbá wọlé, nígbà tí àwọn mìíràn wá láti ṣe ìrànwọ́ fún àwọn àkórí kan…
Ìtalólobó àgbà-ọ̀jẹ̀ fún wíwú gbòǹgbò ìròyìn-èké Láti ọwọ́ Maurice Oniang’o | ọjọ́ kẹtà-lé-lógún oṣù kọkànlá, ọdún 2021 Fún àwọn oníròyìn aṣèwádìí tí wọ́n ń wú ìpòlongo tí ìròyìn tí kò…
Ìròyìn tó dára jù lọ Èyí jẹ́ Ẹ̀rọ ayélujára tó ní onírúurú ohun èlò èyí tí ilé iṣẹ́ ìtẹ̀wé ilẹ̀ Amẹ́ríkà ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀. Ìgbìmọ̀ amúṣẹ́yá AEJMC láti dí àlàfo…
Bíbẹ̀rẹ̀ – Àwọn Àmọ̀ràn ní ìpele ìpele Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Tí o bá ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣé alábàápàdé ìròyìn tó jọ mọ́ dátà, àwọn ohun èlò wọ̀nyí wá…
Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀-Abójú-ayé-mu Ohun-èèlò ọmọ-ẹgbẹ́ 101: Ṣégeṣège Ìtúpalẹ̀ rẹ, kí o sì gùnlé ìrólágbára-ètò àkójọpọ̀-fáyẹ̀wò fún ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ Agbára ìgbóhuntuntunjáde nínú iṣẹ́-ìròyìn ọlọ́gbọnrangandan lórí ìtàkùn-àgbáyé: Àwọn àpẹẹrẹ márùn-ún tó peregedé. Iṣẹ́-ìwádìí àwùjọ…
Láti o̩wó̩ Raymond Joseph | O̩jó̩ Ke̩rìnlélógún, Os̩ù Ògún, 2021 This photograph of a weasel clinging to the back of a flying woodpecker went viral on social media. While it had all the…
Onírúurú ìkànnì tí ìdàgbàsókè ti débá ló wà tí ó ń ran àwọn òǹkọ̀wé lọ́wọ́la ti owó nípaṣè ìgbéjáde-ara-ẹni. Yàlá àwọn wọ̀nyí tọ̀nà fún ọ èyí yóò gbà ìwádìí. Ní…
Ìwé ìléwọ́ fún àwọn oníròyìn ilẹ̀ Lárúbáwá nípa òmìnira à ti kó ìròyìn jọ pẹ̀lú iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn: e yóò rí ìwé olójú ewé mọ́kànlélógún ọ̀hún gbà lọ́fẹẹ̀ẹ́ lórí…
GIJN ti ṣe àkójọpọ̀ àti ètò àwọn ohun èròjà nípa lílo dátà fún ìròyìn tó jọ mọ́ iṣẹ́ ìwádìí. À bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ojúlówó àwọn èròjà ìdánilẹ́kọ̀ọ́ kí a tóó kán…
Láti o̩wó̩ Laura Dixon | April 5, 2021 Ní GIJN, a s̩e oríire láti s̩e alábàápàdé àwo̩n orís̩irís̩i ìwé àti ìròyìn lórí ipò is̩é̩-ìgbóhùnsáfé̩fé̩ aje̩mó̩ròyìn àti ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩ tí ó mó̩yán lórí. Èyí…