ÀÌDÁṢE: Fi Ìsedúró Wéwu
Níní ìṣedúró nígbà tí o wà lórí àwọn iṣẹ́ àyànṣe eléwu le jẹ́ ìkówólé tó mú ọpọlọ dáni àti èyí tí kò wọ́n tó bí o ṣe bẹ̀rù. Rí àwọn…
Níní ìṣedúró nígbà tí o wà lórí àwọn iṣẹ́ àyànṣe eléwu le jẹ́ ìkówólé tó mú ọpọlọ dáni àti èyí tí kò wọ́n tó bí o ṣe bẹ̀rù. Rí àwọn…
Ìròyìn ní èdè agbègbè jẹ́ èyí tí akọ̀ròyìn pẹ̀lú ilé iṣẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ ìlú Canada, Duncan McCue gbé jáde lọ́dún 2011. Ó ń àwọn èròjà láti kọ ìròyìn lédè abínibí jákèjádò…
Àwọn oníròyìn náà ń kíyèsí ìpolówó ìmọ̀-ẹ̀rọ. Àwọn náà sinmi lé e. “CJR” Kín ni ohun tuntun nínú títẹ àádọ́ta àbájáde fún owó iṣẹ́-ìròyìn: àlàyé tó lọ sàn-án (apá kejì).…
Èyí ni àwo̩n ilé-is̩é̩ aláìgbojúlé-èrè tí a bá tan káàkiri àgbáyé tí wo̩n ń s̩e is̩é̩ láti ran ìròyìn ò̩te̩lè̩múyé̩ ló̩wó̩, láti agbègbè sí agbègbè. Ó jé̩ àkójo̩pò̩ tí ó…
Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ Dátà Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Türkçe Ǹ jẹ́ ó fẹ́ kọ́ nípa ọgbọ́n àtinúdá lórí ìwé ìtẹ̀wé? Àwọn ètò ẹ̀kọ́…
DÍDẸ́RỌ́ ÀJÀKÁLẸ̀ ÀRÙN FI ÀÀYÈ SÍLẸ̀ LÁTI WÁ ÌYÀNJÚ SÍ ÀÌṢE DÉÉDÉÉ LÓRÍ LÍLO DÁTÀ Ọjọ́ Kọkàndínlógún, Oṣù Èbíbí, Ọdún 2021 Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ṣe àǹfààní ń lá gbáà fún…
Ìpàdé Àpérò Àgbáyé lórí iṣẹ́ ìwádìí lórí Ìròyìn yóò wà lórí ẹ̀rọ ayélujára ní oṣù kọkànlá, ọdún 2021; Òmíràn yóò wáyé ní ìlú Sydney lọ́dún 2022. Láti Ìkànnì GIJN |…
Ǹ jẹ́ ẹ́ ń wá àmọ̀ràn ní ṣókí, àwọn ohun èlò tàbí ìtọ́ni sónà? Yẹ ìsàlẹ̀ wò fún àwọn ìtọ́sọ́nà tó ní í se pẹ̀lú ìwádìí ìjìnlẹ̀ lórí Ìròyìn pẹ̀lú…
Láàrín àwọn ogunlọ́gọ̀ orílẹ̀-èdè tó bọ́ sí gúúsù aṣálẹ̀ nílẹ̀-adúláwọ̀, àǹfààní sí àkọsílẹ̀ gbogbogbò kìí ṣe ohun tó rọrùn rárá títí dòní, bí-ó-tilẹ̀ jẹ́ pé kò sí àwọn òfin tó…
Turbulent with a chance of data: Journalism’s drone-powered futures: A guide to storytelling with UAVs, láti o̩wó̩ Monica Sengul-Jones nínú datajournalism.com Tips on Drone Journalism, láti o̩wó̩ Raffy Tima tí…