Bí a ṣe lè dá Ikọ̀ tó ṣẹ̀dá iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ dátà
Láti ọwọ́ Fabiola Torres López | Ọjọ́ Kọkànlá, Oṣù Agẹmọ 11, Ọdún 2017 Ní ọdún márùn-ún sẹ́yìn, àwọn akọ̀ròyìn tó ń bojú wo ibi ì kò èròjà sí tàbí wá…
Láti ọwọ́ Fabiola Torres López | Ọjọ́ Kọkànlá, Oṣù Agẹmọ 11, Ọdún 2017 Ní ọdún márùn-ún sẹ́yìn, àwọn akọ̀ròyìn tó ń bojú wo ibi ì kò èròjà sí tàbí wá…
Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Tí o bá ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣé alábàápàdé ìròyìn tó jọ mọ́ dátà, àwọn ohun èlò wọ̀nyí wá lọ́fẹẹ̀ẹ́ fún lílo, tí yóò sì jẹ́…
Ìdáṣe gẹ́gẹ́ bí oníròyìn oníwàádìí jẹ́ ìpèníjà ní àkókò tó dára jù, ó sì tún ṣàfihàn àwọn ìṣòro nígbà àjàkálẹ̀-ààrùn kòrónà. Láti ṣísàkóso ewu ajẹmára sí pípàdánù iṣẹ́ láti ara…
Mímúlò ìtàkùn ayélujára tó níwọ̀n lò ní Yàrá-ìròyìn rẹ: Ewé-ìtalólobó lórí Ìfọ́ńká àti lílọ́wọ́sí àwọn olùwòran Láti ọwọ́ Rossalyn Warren | March 18, 2021 Bí o bá ń ka èyí,…
Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú Python jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun èlò èdè tó gbajúgbajà jùlọ fún àwọn oníròyìn tí iṣẹ́ wọn jọ mọ́ dátà, ó tún wúlò…
Membership in GIJN Ọmọ ẹgbẹ ninu Global Investigative Journalism Network wa ni sisi si awọn ti kii ṣe ere, awọn NGO, ati awọn ajọ eto ẹkọ, tabi deede wọn, ti…
Okan gboogi lara ojuse GIJN ni lati se akojopo atona fun iwadii to m’una d’oko lori Iroyin. Oniruuru awon ede ni e yoo ri, pelu eto eko ati ilaniloye l’oniranran.…
Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú SQL jẹ́ ohun èlò tí wọ́n máa ń lò nígbà gbogbo nígbà tí wọ́n bá fẹ́ ṣiṣẹ́ pẹ̀ lú ibi tí aà ń…
Iṣẹ́ takuntakun tó wà nìdii iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ ìwádìí lè kọ́ ìpèníjà látàrí onírúurú akùdé. Ohun èlò yìí ṣe àgbékalẹ̀ onírúurú ìpèníjà tí àwọn àìfíkítà àti àwọn ilé…
Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ lórí iṣẹ́-àkànṣe aṣèwádìí jẹ́ gbajúgbajà síi lójojúmọ́. Ṣíṣeṣẹ́ pọ̀ pẹ̀lú alábàáṣiṣẹ́ le ṣe àfikún àti ìrànlọ́wọ́ jíjábọ̀ ohun èlò àti ìgbéga ọ̀nà oǹkàwé. Le gba àwọn Ìmọ̀ọ́ṣe tó yàtọ̀,…