Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú
Python jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ohun èlò èdè tó gbajúgbajà jùlọ fún àwọn oníròyìn tí iṣẹ́ wọn jọ mọ́
dátà, ó tún wúlò fún ṣíṣe àfọ̀mọ́ ẹ̀rọ ayélujára, tí kò sì yọ àtúpalẹ̀ dátà sílẹ̀. Dìẹ̀ rèé lára àwọn
ohun èlò láti kẹ́kọ̀ọ́
lórí ìkànnì Python.
Àtúpalẹ̀ díẹ̀ nínú ìkànnì Python jẹ́ ìwé orí ẹ̀rọ ayélujára tó wà fún Ìpilẹ̀ṣẹ̀ fún ìkànnì Python. Ó
wà fún àwọn tí wọ́n ní ìmọ̀ tí kò tò ǹ kan nínú èdè. Ìkànnì yìí tún wá pẹ̀
lú iṣẹ́ ìdárayá lórí GitHub.
Datajournalism.com náà ń pèsè àfihàn sí ìdánilẹ́kọ̀ọ́ lórí ìkànnì Python fún àwọn akọ̀ròyìn tí
wọ́n ń lo àjákọ Jupyter èyí akọ̀ròyìn kàn lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà láti ìlú Netherlands, Winny de
Jong, and ń kọ́.
Ìwé àjákọ Python jẹ́ ìgbésẹ̀ fún atọ́nà tí wọ́n pèsè fún àwọn alákọ̀bẹ́rẹ̀
láti ọwọ́ olóoòótú ìròyìn
ìlú Los Angeles, and tó tún jẹ́ gbajúgbajà lórí Ìròyìn tó jọ mọ́ dátà, Ben Welsh.
Kíláàsì Ìkànnì Python lórí Gọ́gù jẹ́ atọ́ka Ìpilẹ̀ fún Python, pẹ̀
lú àwọn iṣẹ́ ìdárayá tí kò ní kọ́
lú ń
kọ́họ nínú.
Ìkànnì Learnpython.org tí ní àgbékalẹ̀ àwọn ohun èlò ìdánilẹ́kọ̀ọ́ pẹ̀
lú ìfikùlukùn tó tó jíire lórí
ìkànnì Python Shell, láì ṣe wàhálà gbígbà Phyton tàbí ọlọ́rọ̀ wuuru rẹ̀
lórí ẹ̀rọ ayélujára.
Ìdánilẹ́kọ̀ọ́ yìí. Àwọn kókó ọ̀rọ̀ kò dúró ní gọ́gù nìkan..
Kọ́ Nípa Python Kẹta Lọ́nàkọnà (2017) láti ọwọ́ Zed Shaw, jẹ́ àfihàn fún ìfàmìsí pẹ̀lú Python.
Tí wọ́n bá ràá lati orí ẹ̀rọ ayélujára Òǹkọ̀we fúnra rẹ̀, ìwé náà yóò wà pẹ̀lú fọ́nrán ìdánilẹ́kọ̀ọ́
(Béèrè fún tìrẹ)
Padà sí orí ìkànnì ojú ewé iwájú