AsÌpín, Ìgbéga àti Àìfíkítà

Iṣẹ́ takuntakun tó wà nìdii iṣẹ́ ìròyìn tó jọ mọ́ ìwádìí lè kọ́ ìpèníjà látàrí onírúurú akùdé. Ohun èlò

yìí ṣe àgbékalẹ̀ onírúurú ìpèníjà tí àwọn àìfíkítà àti àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn tó dá lórí iṣẹ́ ìwádìí ń fi

ojoojúmọ́ kojú lẹ́nu iṣẹ́ wọn. This resource addresses a number of challenges which are faced

by freelancers and media organizations producing and distributing investigations. Síwájú sí, wo

bí àwọn ohun èlò yìí ṣe ní ipa àwọn ènìyàn, tí ẹ lè rí ní ìkànnì GIJN Sustainability Resource

Center.

Àwọn Ohun èlò fún àwọn Ilé iṣẹ́ Gbogbo

● Àjọṣepò àti Ìfọwọ́sowọ́pọ̀

● Ìdàpọ̀

● Àlékún lílo ayélujára Ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ nínú yàrá ìkóròyìn jọ

Ìpín àti and Àìfíkítà

● Ìpolówó Ìròyìn tó jọ mọ́

iṣẹ́ ìwádìí Polówó

● Ìpolówó Lásìkò Àjàkálẹ̀ Àrùn

● Ibi tí ẹ ti lè

● Ibi tí ẹ ti lè rí Ọwọ́ Ìrànwọ́

● Àwọn Àdéhùn

● Adíyelófò fún Ewu

● Adíyelófò fún Iṣẹ́ Ìròyìn

● Àìléwu àti Ààbò

● Ìkànnì Ìtẹ̀wé fúnra ẹni