gijn-logo

Àlàyé lórí Ìpolówó-ọjà Ìmọ̀-ẹ̀rọ “Tow Center”

Àwọn oníròyìn náà ń kíyèsí ìpolówó ìmọ̀-ẹ̀rọ. Àwọn náà sinmi lé e. “CJR”

Kín ni ohun tuntun nínú títẹ àádọ́ta àbájáde fún owó iṣẹ́-ìròyìn: àlàyé tó lọ sàn-án (apá kejì). Kín ni ohun tuntun nínu ìtẹ̀wétà.

Ìpolówó-ọjà ìkànnì-ayélujára (ní U.S.A.) ń pòórá bí àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ìwé-ìròyìn-àtìgbàdégbà ti bẹ̀rẹ̀ síní kọjáàyè ara wọn “WWD”

Ilé-iṣẹ́-ìròyìn “Financial Times” ṣẹ̀dá irinṣẹ́ ìyànnàná àwùjọ láti ṣàlékún owó tó ń wọlé lemọ́lemọ́ láti ara ìpolówó ọjà “Digiday”

Òpin ayé Ìpolówó-ọjà gẹ́gẹ́ bí a ṣe mọ̀ ọ́n. “Àbọ̀ Nieman”

Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé Ajẹmówò: Ìsanwó-àjọsọ/ àwọn èròjà-àsanwólò

Àwọn ọ̀nà méje tí àjàkálẹ̀-àrùn COVID ṣe nípa àwọn ọgbọ́n-inú fún ìsanwó-àjọṣe.

Bí a ṣe le ṣàgbéró àwòṣe olùkà rere lórí ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé: Àwọn ẹ̀kọ́ láti “Spain” àti “UK”

“Ìjọ́mọ-ẹgbẹ́ kò le gba iṣẹ́-ìròyìn sílẹ̀ nìkan, ṣùgbọ́n yóò tún ràn-án lọ́wọ́ láti gbèrú”: Ìdí tí àwọn atẹ̀wétà fi ń wá ohun tó ju ìsanwó-àjọsọ lọ.

Ìdí tí àwòṣe ìsanwó-àjọsọ fi le má ṣiṣẹ́ fún ọ.

Bí àwọn atẹ̀wétà òde-òní ṣe ṣọ ìlo Àkójọpọ̀-fáyẹ̀wò, iṣẹ́-tó-dára-jù-lọ, ṣàyẹ̀wò-kó-ókọ́gbọ́n ọgbọ́n dàá láti ṣàgbéró ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé tó dára.

Gbígbárùkùti ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé (Àti àwọn ẹ̀kọ́ mìíràn náà láti inú ẹ̀kọ́ àwọn atẹ̀wéròyìn-jáde ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ́ta)

Bí àwọn Yàrá-ìròyìn ṣe le ṣàwárí ìdásí asanwó-àjọsọ àti ìmúdúró Lens Fest.

Ìwé-àyẹ̀wò tí a ṣàmúlò fún odidi irinwó wákàtí lorí àtúpalẹ̀ àwọn asanwó-àjọsọ- èyí ni ohun tí a ṣàwárí “Digital Content Next”

Àkíyèsí ìdókòwò nínú ìsanwó-àjọsọ ti mú èrè ìdàgbàsókè wá pẹ̀lú ìdá ẹgbẹ̀rún-méjì nínú àròpín ọlọ́gọ́rùn-ún “International News Media Association”

Ilé-iṣẹ́ Sanwó-kó-o-tó-jàǹfààní-iṣẹ́ “pay gates” ṣe dáadáa ju “paywalls” lọ, àwọn atẹ̀wéròyìn jáde “Swiss” ló fi èyí hàn. Kín ni ohun tuntun nínú iṣẹ́-ìtẹ̀wéjáde.

Ǹjẹ́ ò ń ṣàgbérò ọgbọ́ndàá sanwó-kó-o-tó-jàǹfààní-iṣẹ́ “paywall” fún ìwámọ̀kúnmọ tàbí ìmúdúró? Twipe.

Bí “News Zurcherv Zertury” ṣe ṣàfikún èrè rẹ̀ ní ílọ́po márùn-ún pẹ̀lú ọlọ́gbọ́n-inú “paygates” “Journalism.co.uk”

Ọ̀nà kan pàtàkì láti ṣàlékún ìsanwó-àjọsọ láti ọwọ́ ìkànnì àgbáyé Gúgù (Google) kín ni ohun tuntun nípa iṣẹ́-ìtẹ̀wéjáde

Kín ni àwọn kọ́kọ́rọ́ sí àǹfààní ojú-ìwé fún ìsanwó-àjọsọ tó jáfáfá? Àjọ oníròyìn Amẹ́ríkà
“Àkàsọ̀ Ìdásí” – Àwọn Ọgbọ́n-inú láti ṣàlékún àwọn asanwó-àjọsọ tuntun Kín ni Ohun-tuntun nínú iṣẹ́-ìtẹ̀wéjáde.

Bí a ṣe le ṣàlékún ìforúkọsílẹ̀ àti ìsanwówọlé ìsanwó-àjọsọ

Ju àtẹ̀jíṣẹ́ orí ìkànnì-ayélujára lọ: Àwọn ọgbọ́ndàá mìíràn láti olùkópa sínú àǹfààní ìsanwó-àjọsọ Àjọ Oníròyìn Amẹ́ríkà

Èyí ni ọ̀nà kan tó rọrùn láti mọ̀ bóyá ó ṣeé ṣe kí olùkà sanwó-àjọsọ Nieman.

Ohun tó gbà láti sún àjọ oníròyìn sí ìpawówọlé olùkà: Àjọ Oníròyìn Amẹ́ríkà ìtọ́sọ́nà ráḿpẹ́ sí àwọn ìdojúkọ gbòógì tó máa ń dìde nígbà tí a bá ń ṣàgbérò ètò ìsanwó-àjọsọ.

Bí àwọn atẹ̀wéjáde ṣe le ṣàlékún ìpawówọlé wọn pẹ̀lú Àpótí Ìsanwó-àjọsọ, Abala Kẹta “Aláṣẹ Ìtẹ̀wéjáde”

Ílépa Ìpawówọlé-olúkà jẹ́ ohun tó ṣeé ṣe

Bí ilé-iṣẹ́-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde “Paywalls” ṣe ń ṣiṣẹ́ ní àwọn orílẹ̀-èdè Apàṣẹwàá.

Àwọn ìtalólobó mẹ́ta láti ṣàtúpalẹ̀ àwọn ọ̀nà-àbáyọ “Paywalls”

Àwọn ipa-ọ̀nà fún ìsanwó-àjọsọ: Ìdí tí àwọn asanwó àjọsọ sáà yìí fi yan sísanwó fún ìròyìn.

Bí àwọn atẹ̀wéjáde alásanwó-àjọsọ ṣe ń gbìyànjú láti jẹ́ kó jẹ́ ìwà àwọn ọ̀dọ́ láti máa sanwó fún àkóónú.

Àwọn ajábọ̀ ti ṣiṣẹ́ tako “paywalls” rí, àti èsì rẹ̀ fún wọn.

Ìbòsí o, “Paywall” ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣèràpadà: Èyí ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀nà tí àtúnṣe yìí fi le bá àkóónú-tó-o-sanwó-fún wí.

Oríṣìí mẹ́ta àwọn asanwó-àjọsọ fún ìròyìn: Ìdí tí wọ́n fi ń sanwó àti bí a ṣe le pè wọ́n wọlé.

Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé Ajẹmówò: Ìsanwó-àjọsọ / “Paywalls” – Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ Abójú-ayé-mu.

Ìdí tí àlàyé ọgbọ́n-inú “Paywall” fi ṣe àṣeyọrí.

Iye asanwó-àjọsọ mélòó lo nílò láti mú ìwé-ìròyìn-àtìgbàdégbà agbówómì kúrò? “Arkansas Life” ṣàwárí “Nieman Lab”

Bí iṣẹ́-ìròyìn ìsanwó-àjọsọ ìtajà-ohun-tójú-rí ṣe Rí The Ken.

Ọdún 2018 jẹ́ ọdún àṣeyọrí gbòógì fún àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀ (bí-ó-tilẹ̀-jẹ́-pé- ọ̀kan ṣoṣo nínú márùn-ún ni a ṣèrànwọ́ fún) Nieman

Àwọn Ojú-inú àkójọpọ̀-fáyẹ̀wò láti ọwọ́ ọ̀kan lára àwọn gbajúgbajà ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn tí kò pójú-owó WAN

Ṣíṣàfihàn ìròyìn: Bí àwọn ilé-iṣẹ́ ìròyìn ìkànnì-ayélujára “Atlantic and Zeit” ṣe ṣe é GENInnovate.

“Àwọn ènìyàn rò pé orí wa kò pé láti ṣàmúlò “paywall” ni olórí ìròyìn-ìgbàlódé “Times” sọ nígbà tó tọ́ka sí “Smart” fún ìsanwó-àjọ fún sísanwó àkóónú lọ́jọ́-iwájú.

Ilé-iṣẹ́-ìròyìn “Winnipeg Free Press” ti ṣe àṣeyọrí pẹ̀lú àwòṣe tó jẹ mọ́ àwọn ìgbà ìdojúkọ ìsanwó-àjọsọ àti ọ̀nà-ìsanwó-kékeré.

Ilé-iṣẹ́ ìròyìn “Guardian”Ǹjẹ́ iṣẹ́-ìròyìn le fi ẹsẹ̀ múlẹ̀ bí i bàtà-àwọ̀ṣeré-ìdárayá bí?

Bí àwọn inímọ̀-ọrọ̀-ajé ṣe lo ẹgbẹ́ iṣẹ́-ìròyìn àkójọpọ̀-fáyẹ̀wò ẹlẹ́niméjìlá ṣàlékún owó-àjọsọ.

Ìkànnì-ayélujára “Google” ṣàgbéjáde àwọn irinṣẹ́ ìsanwó-àjọsọ tuntun pẹ̀lú ìkànnì-àgbáyé ilé-iṣẹ́ ìwé ìròyìn “MC Clatchy”

Ìdajì owó-tó-ńwọlé fún ìjọba Yúròòpù wá láti inú owó-àjọsọ sísan.

Ilé-iṣẹ́ ìròyìn “Polish Daily Gazeta Wyborcza” làlùyọ nínú àfojúsùn wọn lórí ìsanwó-àjọsọ ìgbàlódé.

Iye tí àwọn ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn nílẹ̀ Amẹ́ríkà dá lé ìsanwó-àjọsọ ìgbàlódé wọn.

Kìí ṣe gbogbo àwọn oníbàárà ìwé-ìròyìn ló ń san owó kan náà. “Schibsted” ń gbìyànjú láti ṣàfàyọ àwọn tí yóò sanwó jù lọ.

Bí àwọn ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn Amẹ́ríkà tó ti lààmì laaka ṣe ń rí àwọn ènìyàn sanwó fún ìròyìn.

Bí àwọn agbéròyìnjáde “Media part” ti ṣàmúlò rògbòdìyàn òṣèlú ṣàlékún owó-àjọsọ wọn.

Bí àwọn oníròyìn “Shvak” ṣe fi ìwé wọn sílẹ̀ tí wọ́n sì ṣàgbéró ìfigagbága àìrọ̀gbọ̀kúléjọba pẹ̀lú àwọn asanwó-àjọsọ ìgbàlódé tó tó ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélógún.

Èyí bí àwọn oníròyìn náwè ṣe ṣàgbéró owó-àjọsọ ìgbàlódé aláṣeyọrí àwòṣe fún ìròyìn alábọ́dé.

Ìkànnì ìsanwó-àjọsọ ìròyìn-kan-lójúmọ́. Ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn “The Ken” pa mílíọ̀nù kan àti ààbọ̀ dọ́là.

Ilé-iṣẹ̀ ìwé-ìròyìn “The Ken” ní India ń gbé ìròyìn ọlọ́gbọnrangandan kan jáde ní ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀. Ní báyìí, àwọn asanwó-àjọsọ ń sanwó láti ọkàn wọn wá ni.

Àwọn ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn “The Ken” lòdì sí èrò “The Grain” láti máa gbé ìròyìn ọlọ́gbọnrangandan kan jáde ní ojoojúmọ́ àti ọ̀nà ìsanwó àkóónú “Paywall”.

Bí ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn “The Times of London” ṣe mú ìgbèrú bá àwọn tó forúkọ sílẹ̀ pẹ̀lú wọn di mílíọ̀nù kan àti ẹgbẹ̀rún lọ́nà igba.

Bí mẹ́rin nínú àwọn àkóónú owó-àjọsọ tó wọ́n jù lọ ṣe parapọ̀.

  • Ọ̀nà-tówó-ń-gbà-wọlé Ajẹmówò: Ìgbówò-lárugẹ, ìtẹ̀wéjáde, ìdòwòpọ̀, Ẹ̀tọ́-fọ́jà-títà.

Iṣẹ́-ìròyìn oníwàádìí ń ṣe àmúlò eré-ìdárayá alágbèéká láti ṣèrànwọ́ ètò-ìsúná fọ́jọ́wáájú rẹ̀.

Ilé-iṣẹ́ ìròyìn le kọ́ ẹ̀kọ́ kan tàbí méjì láti ara “Netflix”

“CIR” ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣàgbéjáde ìròyìn oníwàádìí lórí ìwé-ìròyìn. Ó ti ń ṣiṣẹ́ lórí eré-àgbéléwò ilẹ̀ Amẹ́ríkà náà báyìí.

Àwọn ajábọ̀-ìròyìn mọ́kànlélọ́gọ̀rún-ún ń ṣe àgbékalẹ̀ àjọṣepọ̀ àwọn oníròyìn jákèjádò India pẹ̀lú àwọn àjọ-tó-ń-gbé-ìròyìn-jáde tó nílò ìròyìn wọn.

Ilé-iṣẹ́ ìwé-ìròyìn “Buzzfeed” ti ní àwòṣe okoòwò tuntun, ó sì ń ta àwọn ohun-èèlò Yàrá-ìdáná ní “Walmart”

“Ẹ̀tọ́ àti ojúṣe tó o ní lórí àkóónú iṣẹ́ rẹ̀ ni ọjọ́-iwájú rẹ̀. Ṣàkóso rẹ̀!” 

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *