Àìléwu àti Ààbò

Àkójọpọ̀ ìṣìrò korò: àwọn oníṣẹ́-ìròyìn tí ó ju egbèje lọ ní ó di pípa ní 1992, pẹ̀lú àwọn tí wọ́n dojú ìjà kọ tí wọ́n sì ṣe inúnibí sí ju ẹgbẹ̀rún lọ. Bẹ́ẹ̀ sì ni, àwọn ìbára-ẹni-sọ̀rọ̀ wa kò tíi ṣe àìní-ààbò tó. Èyí ni àwọn ohun ìtọ́nisọ́nà láti GIJN àti àwọn akẹgbẹ́ rẹ̀ lórí ìdáàbò ojúkorojú àtí ààbò ẹ̀rọ. Ohun àfikún ni ohun ìtọ́nisọ́nà sí òmìnira àwọn oníròyìn jákè-jádò àgbáyé tó ṣe pàtàkì àti àwọn ẹgbẹ́ ààbò.

  • Áwọn ìgbésẹ̀ kòṣeémáṣe bí ó bá ní láti sá kúrò ní orílẹ̀ èdè rẹ 
  • Irinṣẹ́ fún àgbéyẹ̀wò ààbò àwọn oníṣẹ́-ìròyìn
  • Àìléwu àti ààbò: àwọn ìtọ́nisọ́nà àti àwọn àjọ
  • Kíkó ìròyìn jọ lórí ìfẹ̀họ́núhàn lópòópónà
  • Dídáàbò bo ara ẹni lórí ẹ̀rọ ayélujára.
  • Ààbò ẹ̀rọ ayélujára.