gijn-logo

A Taste for Trouble

“Fífi ọwọ́ fà wàhálà láti”  ọwọ́ Aniruddha. Ní ogún ọdún sẹ́yìn, Bahal dá ẹ̀fúùfù àgbáyé èyí tó ń ṣe ìwádìí lórí à ì ṣe déédéé tó ń wáyé láàárín àwọn eléré ìdárayá kíríkẹ́ẹ́tì sílẹ̀. Ọwọ́ yẹpẹrẹ kò ṣeé fi mú kí kojú àwọn aláṣẹ tó ń darí ìdárayá nílẹ̀ India, Bahal fako yọ pẹ̀lú orúkọ tó gbà fún ara rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi “bàbá fún iṣẹ́ ìròyìn tó ń jóni wàhì-wàhì nílẹ̀ India.” Ìwé tuntun tó ṣẹ̀ṣẹ̀ ṣé tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ “Fífi ọwọ́ fà wàhálà láti” ló kọ lásìkò kí onílé ó gbé lé, tó sì yàn náà gbogbo àsìkò ìgbà èwe rẹ̀, títí di ìgbà tó dá ilé iṣẹ́ tó ń ṣe ìwádìí lórí Ìròyìn tirẹ̀ sílẹ̀ (ẹ̀ka GIJN Cobralost), “lásìkò tí ó nira fún àwọn ilé iṣẹ́ ìròyìn láti sọ òdodo” , gẹ̀gẹ̀ bí ìwé ìròyìn Hindustan ṣe sọ. 

Leave a Comment

Your email address will not be published. Required fields are marked *