ÀÀBÒ. DÍDÁÀÀBÒ BO ARA ẸNI LÓRÍ Ẹ̀RỌ AYÉLUJÁRA FÚN ÀWỌN ONÍRÒYÌN: ÌFÁÀRÀ
Láti ọwọ́ Martin Shelton | ọjọ́ kejìlá oṣù kẹjọ, ọdún 2016 Ṣọ́ ògiri rẹ. (Peter Levy) Dídáààbò bo ara ẹni láìsọ ọkàn rẹ nù Àtẹ àwọn ohun èlò òǹkọ̀wé wà…
Láti ọwọ́ Martin Shelton | ọjọ́ kejìlá oṣù kẹjọ, ọdún 2016 Ṣọ́ ògiri rẹ. (Peter Levy) Dídáààbò bo ara ẹni láìsọ ọkàn rẹ nù Àtẹ àwọn ohun èlò òǹkọ̀wé wà…
Ohun Tó Yẹ Ní Ṣíṣe Lásìkò Tí Àwọn Aláṣẹ/ Agbófinró Já Wọ Inú Ilé Rẹ. Láti ọwọ́ Julia Krasnikova | Ọjọ́ kejì-lé-lógún oṣù kẹrin, ọdún 2021 Roman Anin (lọ́wọ́ ọ̀tún),…
Ǹjẹ́ o ń wá àyè láti ṣe ìgbéga sí ìmọ̀ọ́ṣe rẹ àti kí o fẹ àgbáyé lójú? Ó fẹ́ fọ́ iṣẹ́ ojoójúmọ́ nínú yàrá-ìròyìn kí o sì ṣe ìdàgbàsókè iṣẹ́…
Ohun tí àwọn Oníròyìn nílò fún ìkóròyìn jọ tó dára lásìkò Àjàkálẹ̀ Ààrùn Tókárí-ayé COVID- 19 ti ṣe ìwúrí fún idàgbàsókè àkójọ olùgbówósílẹ̀ láti ṣe ìfúnni sí àwọn Oníròyìn. Ń…
Owó-ìrànwọ́ àti Ìdàpọ̀-ọ̀rẹ́ fún àwọn oníròyìn Owó-ìrànwọ́ tó níṣe pẹ̀lú COVID-19 Ò ń wá ààyè láti ṣe àtúnṣe sí ìmọ̀ọ́ṣe rẹ àti láti fẹ ayé rẹ lójú? Iṣẹ́ ojoojúmọ́ ti…
Ìwé Àkọsílẹ̀ Iṣẹ́ Ìwádìí ń pèpè fún iṣẹ́ ìwádìí tó dá lé àkójọpọ̀ dátà fún COVID-19 Ìwé Àkọsílẹ̀ lórí iṣẹ́ ìwádìí fún àkójọpọ̀ dátà lórí COVID-19 kan tí kéde àwọn…
Ni èyí tí àjọ Samir Kassir tó kalẹ̀ sí ìlú Beruit ṣe àgbékalẹ̀ rẹ̀, atọ́nà lórí àwọn abẹ̀mí ni wọ́n gbé kalẹ̀ láti ṣe ìrànwọ́ fún àwọn akọ̀ròyìn àti àwọn…
Ń wá àwọn ohun èlò láti 2021 Global Investigative Journalism Conference? O ti wá sí ibi tó tọ́. Tẹ ibí yìí. O ó rí tó ojú-ewé igba, àwọn ìgbékalẹ̀, àwọn…
Láti ọwọ́ Smaranda Tolosano | Ọjọ́ kejì-dín-lógún oṣù kẹjọ, ọdún 2021 Ìmúdójú-ìwọ̀n tó kẹ̀yìn: Ọjọ́ ọgbọ̀n oṣù kẹjọ Ní akitiyan láti ran àwọn oníròyìn àti àwọn yòókù tó ń gbìyànjú…
Láti ọ̀dọ Rowan Philip | ọjọ́ kẹtà-dín-lógún oṣù karùn-ún, Ọdún 2021 Harvey Weinstein lẹ́yìn ìgbà tí ó fara hàn ní Ilé-Ẹjọ́ ní New York. Wọ́n padà sọ ọ́ sí ẹ̀wọ̀n,…